Menu
13
9ja_gist

OGBAGBA || 65TH YEAR ON THE THRONE

Post image

This day in history, April 2nd 1960, His Royal Majesty Oba Sikiru Kayode Adetona Ogbagba ll ascended the throne as the 55th Awujale of ljebu Land.

Congratulations Kabiesi jebú omo aláre,

Omo arojo joye, Omo alágemo merindinlogún,

Omo aladiye ogògòmógà,

Omo adiye bàlókùn,

Ara drokùn,

Ara ò radiye,

Omo ohun séni,

òyòyò mayòmo ohun séní,

olèpani, omo dúdú ilé komobe se niJósí,

Omo moreye mamaroko, morokotan eye mátilo,

Omo mo ní isunle mamalobe,

ọbe tin be nílé kò mọ ilé baba tó bí wọn lọmo,

Omo onígbò ma'de,

Omo onígbò mawo mawo,

Omo onígò ajoji magbodowo,

Àjòjì tobawo gboro yio di ebora ile baba tobi wan lomo. lièbú omo èrè níwà,

Omo olówó isembayé,

Òrisà jé n dàbí onílé yi,

kelebe ljebú owó,

ìtò lièbú owó ,

Dúdú ljebú owó ,

Pupa ljebú owó,

Kékeré lệbú owó ,

Àgbà ljệbú owó.

lièbú ode ljebú ni,

liệbú igbó liệbú ni,

liệbú isara ljebú ni,

Ayépé ljebú,

Ikorodu ljebú ljebú ní se,

liệbú Qmo oní llé nlá,

liệbú Omo aláso lá...Kaaaabiesi Ooo